Temiloluwa – My Prayer (Lyrics, Mp3 Download)
Contents
Based In African, Popular Gospel Music Minister Temiloluwa Releases a New Song in September, 2021 Titled “My Prayer” with Mp3 Download and Lyrics
This Song is an Undiluted Praise Medley that deserves your attention, Available on all digital platforms.
Mp3 Download for My Prayer by Temiloluwa
My Prayer Lyrics
Eledumare
Moti duro lenu ona
Mogboju mi soke
Gege bi omo ileri ti o fise
Wase temi funmi
Chorus:
Eledumare se se
Eledumare se se
Eledumare se temifunmi (2x)
Iwo nikan lo le soromidayo eledumare se temifunmi (2x)
Verse 1:
Bi iranlowo eda badopin talole gbami ooo,
Iwo mo sa towa oluwa wa ran mi lowo
Mogbeke mi le o baba setemifunmi
Mogbeke mi le o olorun gbo adura miii
Chorus:
Eledumare se se
Eledumare se se
Eledumare se temifunmi (2x)
Iwo nikan lo le soromidayo eledumare se temifunmi (2x)
Verse 2:
Mo mope o lo lese Jehovah,
Kosi ohun ti Iwo kole se
Oku lasaru ojo keta oti ra,
Oti ru sugbon sibe ojidide,
Awon Ise iyanu to tise talole kawan tan
Setemifunmi
Gege bi omo ileri timo je
Wa se temifunmi
Chorus:
Eledumare se se
Eledumare se se
Eledumare se temifunmi (2x)
Iwo nikan lo le soromidayo eledumare se temifunmi (2x)
Bi ireti badopin ti kosi oluranlowo Iwo nikan lo le se
Bi ireti badopin, afi Iwo, afi iwo nikan lo le bamise
Eledumare
Temiloluwa – My Prayer (Lyrics, Mp3 Download)
Follow Us On Facebook InstagramTwitter