Download: Tope Alabi Oluwa Anu Re Duro [Mp3 + Lyrics]

Download: Tope Alabi L’oro L’ero Ati Ni’se [Mp3 + Lyrics]

Nigerian gospel songs

Download L’oro L’ero Ati Ni’se by Tope Alabi [Mp3 + Lyrics + Video]

Download: Tope Alabi L’oro L’ero Ati Ni’se [Mp3 + Lyrics]

Nigerian gospel Music Minister and song writer Tope Alabi drops a Powerful new Album titled Hymnal Vol. 1 few weeks after she celebrated her birthday. L’oro L’ero Ati Ni’se is one of the tracks.

The Album was produced by Dekunle Oniyo and Has 8 different tracks.

Mp3 Download for L’oro L’ero Ati Ni’se by Tope Alabi

L’oro L’ero Ati Ni’se Lyrics by Tope Alabi

Verse 1:
Emi ofe o oluwa, agbara a’tapata
Iwo ni igbalami, ilu olodi mi
Ile iso mi giga, towo ota kole kan
ofami jade wa lati inu omi nla
Titi lemi o fe loro lero nise

Chorus:
Loro lero ati nise Loro lero ati nise
Loro lero ati nise Loro lero ati nise

Verse 2:
Emi o fe o oluwa, Iwo ni iranwo mi
Emi o gbekele e o, igbala owo’tun re
Iranwo re yo mumi d’ro sinsin
Awon elomiran gbeke won le keke ogun
Sugbon emi gbekele loro lero nise

Verse 3:
Emi o mayo s’oluwa, oba ati ase mi
Fi’bukun fun oluwa, anu re duro titi
Ofi ade demi o komi lona re
Ola at’ojo gigun lo jogun fun mi
Ope mi yo po loro lero nise.

Video

Download Audio

Gospellife Download

This is not Your downloading link is above this button or below, and states " Download Mp3 or Mp4"

Gospellife Download


Gospellife is a website to download Mp3, Video, Mp4 Lyrics, Biography and Instrumentals for both Nigerian and Foreign gospel songs.
Related website to Gospellife Includes [Gospelsongs, Jesusful, Gmusicplus, gospellyricng, Muslyrics, Nicegospel, gospelvibes, Naijaloaded, Dailygospelvibes and gospelminds]

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *