Download: Mosun Olaitan Olorun To Tobi [Mp3 + Lyrics]

Download: Mosun Olaitan Olorun To Tobi [Mp3 + Lyrics]

mp3 download Nigerian gospel songs

Download Olorun To Tobi by Mosun Olaitan [Mp3 + Lyrics + Video]

Download: Mosun Olaitan Olorun To Tobi [Mp3 + Lyrics]

This song is virtually on the playlist of many Christian and some Choir cant do without singing the song during Church worship session.

Olorun totobi has been remix and re sang by many gospel artist including Yinka Ayefele and Femi Solar but Mosun Olaitan is the Original Owner of the song.

The meaning of the song is “A big God/A great God

Mosun Mola Olaitan also delvers Iyanu Ni

Mp3 Download for Olorun To Tobi by Mosun Olaitan

Olorun To Tobi Lyrics by Mosun Olaitan

{Mosun Olaitan alone}
Baba to ju baba nla wa
Ogborun ro Kofi teni kankan se
Araba ribiti arugbo igbani
Baba to ju baba nla wa lo

Baba tofi idi aye sole
Ogorun ro Kofi teni kan se
Araba ribiti arugbo igbani
Baba to ju baba nla wa lo

[Chorus]Olorun to tobi Olorun baba agba
Olorun to tobi Olorun baba agba
Aye ogba o Oforun se ibugbe
Aye ogba o oforun se ibujoko
Olorun to tobi Olorun baba agba

{All sings}
Baba to ju baba nla wa
Ogborun ro Kofi teni kankan se
Araba ribiti arugbo igbani
Baba to ju baba nla wa lo

Baba tofi idi aye sole
Ogorun ro Kofi teni kan se
Araba ribiti arugbo igbani
Baba to ju baba nla wa lo

{Chorus and Adlib}
Olorun to tobi Olorun baba agba
Olorun to tobi Olorun baba agba
Aye ogba o Oforun se ibugbe
Aye ogba o oforun se ibujoko
Olorun to tobi Olorun baba agba

{Chorus and Adlib}
Olorun to tobi Olorun baba agba
Olorun to tobi Olorun baba agba
Aye ogba o Oforun se ibugbe
Aye ogba o oforun se ibujoko
Olorun to tobi Olorun baba agba

Mosun Olaitan Olorun To Tobi

Emi ni emi ni ti nje emi ni
Emini majaya lolo
Otobi Otobi
{Repeat Chorus}
Olorun to tobi Olorun baba agba
Olorun to tobi Olorun baba agba
Aye ogba o Oforun se ibugbe
Aye ogba o oforun se ibujoko
Olorun to tobi Olorun baba agba

{Eulogy}
Oba ti nbe nibi gbogbo
Nigbakan soso
Agbenu aye sola agbenu Orun sogo
Obiri ki aji pojo iku da eleda meda


Olowo gbogboro o ti nyomo re ninu Ofin aye
Okan soso araba ti nmi gbo kijikiji
Alapa kabi kabi
Olowo j en ba o se
baba mi toloyun ara re totun sora re loruko

Video

Download Audio

Gospellife Download

This is not Your downloading link is above this button or below, and states " Download Mp3 or Mp4"

Gospellife Download


Gospellife is a website to download Mp3, Video, Mp4 Lyrics, Biography and Instrumentals for both Nigerian and Foreign gospel songs.
Related website to Gospellife Includes [Gospelsongs, Jesusful, Gmusicplus, gospellyricng, Muslyrics, Nicegospel, gospelvibes, Naijaloaded, Dailygospelvibes and gospelminds]

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *