Download Shola Allyson - Child [Mp3 + Lyrics]

Download Afuye gege – Iba by Shola Allyson [Mp3 + Lyrics]

Nigerian gospel songs

Download Afuye gege – Iba by Shola Allyson [Mp3 + Lyrics]

Download Afuye gege - Iba by Shola Allyson [Mp3 + Lyrics]

Nigerian gospel music minister and song writer Shola Allyson is here with a powerful new song Iba also known as Afuye gege ti ose gbe

This is a worship song that describes the supremacy of God

She also sang Mimo, Aseye, Lori ile yi, Ebe, Wa wole, Igbagbo, Isinmi

Download Afuye gege

Mp3 download for Afuye gege – Iba by Shola Allyson

Download Music

Lyrics of the song

[Verse1] Ibare ni maa faye miju
Sisin Oo lemi a figba mise
Shebi iyen nooni Iyen gangan sha lo da mi fun
Eni ayeraye to nigba mi oo Ogo foo ko Re

[Chorus] Afuye gege tio she gbe
jigbin ni jigbin ni bi ate ileke
Kabiesio mo seba Re Oba to ju gbogbo oba lo
Kabiesio mo seba Re Oba to ju gbogbo oba lo
Mo seba Re o, mo seba Re
Mofori bale mo gbowo soke
Mo seba Re o, mo seba Re
Nirele okan mo wa ri
Kabiesi o mo seba Re
Oba to ju gbogbo oba lo
Kabiesi o mo seba Re
Oba to ju gbogbo oba lo

[Verse 2] Talo leso ta lo le ka won,
awon irawo towa loju orun
Egbe isiro leewon ke so fun wa
awon erupe inu okun
Talo le so talo moye
ewa iseda toyi wa ka
Iyanu fun dudu iyanu fun fufun
Ose fe ni to gbon ateni to go
Kaabiesi o mo se ba Re o
Oba to ju gbogbo oba lo

[Chorus] Afuye gege tio she gbe
jigbin ni jigbin ni bi ate ileke
Kabiesio mo seba Re Oba to ju gbogbo oba lo
Kabiesio mo seba Re Oba to ju gbogbo oba lo
Mo seba Re o, mo seba Re
Mofori bale mo gbowo soke
Mo seba Re o, mo seba Re
Nirele okan mo wa ri
Kabiesi o mo seba Re
Oba to ju gbogbo oba lo
Kabiesi o mo seba Re
Oba to ju gbogbo oba lo

Gbo gbo aye gbohun soke nimu ewa won, won fogo fooko Re
Ohun gbogbo fiyin fun o o iwo nikan loba tologo
oju mi tiri eti mi ti gbo iyanu re yi aye ka
mogbo ninu eri awon eniyan mimo
mori ninu itan emi gangan onitan
gbogbo ise re dadada ni aburu Kankan o todo Re wa
ohun gbogbo lole yi pada sugbon rara tododo Re ko
kaabie si o moseba Re oo oba toju gbogbo oba lo ee

[Chorus] Afuye gege mama se gbe
Okan mi pongbe mimoo si
Emi wao mo n wa o si oo hmm
Oba toju gbogbo oba lo ogo Re yi aye ka
Emi seba mo sebaoo, mofori bale niwaju ite aanu
oba agbanilagbatan
oba adani magbagbe eni
Mo wa riiiiii
Emi seba Re oo oh oh oh

Call: Oba to ju gbogbo oba lo hmmm
Resp: Oba to ju gbogbo oba lo
Call: Oba toju gbogbpo oba lo sara Re re ooo
Resp: Oba to ju gbogbo oba lo
Call: Ehn kayie sio mose baRe o
Resp: Oba to ju gbogbo oba lo
Call: Emi yio ma fibukun fun o
lojojumo iwo nikan loni ii
Resp: Oba to ju gbogbo oba lo

Call: Ni gbogbo igba ni gbogbo asiko
okan mi yio ma fogo fooko re
Resp: Oba to ju gbogbo oba lo
Call: Oluwa orun ohunaye ewa re yi
aye ka anfogo fooko re hmm
Resp: Oba to ju gbogbo oba lo
Call: Mojewo mojewo re iwonikan loluwa
koselomiran leyin re
Resp: Oba to ju gbogbo oba lo
Call: You are beautiful beyond description
ewa re koja ogbon ori
Resp: Oba to ju gbogbo oba lo
Call: You are wonderful beyond comprehension
iyanu re koja oye
Resp: Oba to ju gbogbo oba lo

Video Shola Allyson – Iba (Afuye gege)

 

About the song

The song describes God as a simple God yet explainable, Shola Allyson made it known that wonderful works of God is in-expendable and unimaginable,

Shola Allyson Also describes God as the king of Kings and the Lord of Lords who makes decision and no man can question.

Hope you enjoyed The Mp3 Download of Afuye gege

Download Audio

Gospellife Download

This is not Your downloading link is above this button or below, and states " Download Mp3 or Mp4"

Gospellife Download


Gospellife is a website to download Mp3, Video, Mp4 Lyrics, Biography and Instrumentals for both Nigerian and Foreign gospel songs.
Related website to Gospellife Includes [Gospelsongs, Jesusful, Gmusicplus, gospellyricng, Muslyrics, Nicegospel, gospelvibes, Naijaloaded, Dailygospelvibes and gospelminds]

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *